Oga

HON. HAMMED IDOWU DANIEL TIJANI (HID)

ALAGA
Ojokoro Local Council Development Area

ORO LORI HON.HAMMED IDOWU D.TIJANI (H.I. D).

I’ll Eko ni a bi Hon. Tijani si,o wa lati idile ebi Alhaji Tijani Ayedero ni ojo kefa osu kewa odun 1967.

Hon. H.I.D, lo si Ile iwe alakobere Christ Apostolic Church Odo ona ni ilu Ibadan Lati odunSchool 1976 si Odun1982.

Leyin naa ni o tesiwaju ninu Eko re lo si Ile iwe Baptist Grammar idi isin ni

Ibadan.Ibi ni o ti se idanwo oniwe mewa (WASSCE) ni odun 1987.

Hon. Tijani je eniyan ti o feran Eko pupo, o tun tesiwaju lo si Ile eko akosemose Ladoke Akintolal ni ilu Oyo.

Hon. Hammed tun je okan lara awon akawejade Yunifasiti Ipinle Eko (LASU),Idi re ni Ile iwe ni o ti ka iwegboye lori bi a se amojuto okoowo ni odun 2010.

Hon.Tijani ti awon eniyan maa n pe ni H.I. D je eniyan ti o feran aseyori ,idi re ree ti o fi lo fun awon orisiri eko ni Ile yii ati ni Ile okere eyi ti o fi je lori eto iselu,ati ebi je irorun fun in lati se amojuto.

Eto iselu ati isejoba Hon. H.I. D Tijani bere ni odun 1989 si odun 1990,nigba ti o nsise ni ibi ibudoko oju omi ni Apapa.Leyin naa ni o wa je amugba leave alaga oko oju omi ni Ipinle Eko (Lagos State Ferry Service Corporation) Oloogbe Hon.Saliu Olaitan Mustafa. O tun se amugbalegbe fun Oloogbe Barr.R.A Baruwa ati Engr.Akinyemi Berkeley ebi ti o je alaga nigba yen fun Lagos State Electricity Board lati odun 1991si odun 1994.

Awon eko oniyebiye ni pa iselu ti o wa lara awon ogbontarigi oloselu meta ti Hon.Tijani ba side ni o fa iwuri fun un lati gba opo

Akowe egbe  iselu ni Agege ni igba oselu National Republican Convention (NRC)lati odun 1990siodun1994.

Ni odun 1998.Hon.Tijani gbe apoti oye kanselo lati se amojuto ward  J ni ilu Ifako/Ijaiye,o si jawe olubori labe asia egbe Alliance for Democracy (A D).Leyin eyi ni won tun yan an fun Alamojuto eto Eko ni ijoba idagbasoke Ojokoro ni abe Action Congress (AC)ni odun 2004 si odun2007.

Fun ise takuntakun,iteriba ati ifarasin fun ilu ati awon eniyan ni o mu ki awon fun un ni opo igbakeji akowe ijoba idagbasoke Ojokoro ni abe egbe oselu Action Congress of Nig.(ACN)ni eemeji lera,laarin Odun 2008 si Odun 2014.

Gege bi ojogbon onisoowo ti o peye ,Hon.Tijani ni oludari awon ileese kereje bio DINIHIT FOCUS VENTURE NIG.LTD.Ile ise ti o wa fun okoowo ni Ile  yi ati lagbaye.

Omo egbe rere ati ololufe egbe oselu ALL PROGRESSIVE CONGRESS (APC) lati ibere ni Hon.HID je.

O ti gba awon ami eye ni onirananran lati igba ti o bere ise alaga,lara awon ami eye naa ni oye alaga ti o ni amojuto July ni Ipinle Eko,ati beebeelo